Yorùbá Insights
Níbiyíi ìwọ yóò rí díẹ̀ nínú àwọn ìmọ̀ràn tó tí ní ìlọsíwájú àti àwọn ẹ̀tàn fun ilowosi pípé ní èdè Yorùbá, nitorinaa, kò sí òhun tí o takò Awọn Itọsọna kikọ wá níbí, rántí là tí má fí sí lílo.
Àwọn Fáwélí àti kọńsónántì tí ó wà nínú èdè Yorùbá
Fáwélí Yorùbá pín sí ọnà méjì, àwọn náà níí
1. Àiranmúpè
2. Àránmúpè
* Fáwélí Àiranmúpè; À, E, Ẹ, I, O, Ọ, U
À - Ajá
E - Erin
Ẹ - Ẹyẹ
I - Imú
O - Owó
Ọ - Ọwọ
U - Ooru
* Fáwélí Àránmúpè; AN, EN, IN, ON, UN
Àpẹrẹ:
AN - Ìbhàdàn
EN - Ìyẹn
IN - Erin
ON - Ìbọn
UN - Ìbùsùn (bed)
kọńsónántì; B, D, F, GB, H, J, K, L, M, N, P, R, S, Ṣ, T, W, Y
Pàápàá, ìwúlò àmì èdè Yorùbá ṣe pàtàkì nínú lilo làti kò òrò èdè Yorùbá
Aṣilo ọrọ | Àwọn ọrọ tó tọ́ | Lilo nínú gbólóhùn ọrọ |
Omo, omoh | ọmọ | ọmọ ológo |
se, shey | ṣe | Ṣe o mọ pé mo féràn rẹ? |
Oshey, ose | Oṣé | Oṣé gànn ní |
Ise |
Ìṣẹ́ | Ìṣẹ́ mí ń lọ déédé |
Aye | Ayé | J’yé lọ |
Awon/ won |
Àwọn/ wọn | Àwọn áńgẹ́lì/ wọn wípé |
Ose, oshey | Oṣe | Oṣe lọpọlọpọ |
Jowo | Jọwọ | Baby mí, jọwọ, jẹ ka jọ má gbádùn |
Jor, jo | Jọọ | Jọọ , má bínu |
Ori |
Orí | Orí mí gbémí débẹ |
Emi-Mimo | Ẹmí-Mímọ | Ẹmí-Mímọ, jọwọ, bale mí |
Owo, owoh | Owó | Torí owó ní kókó |
Owo, owoh | ọwọ | Bàbá ọrọ àyé mí ọwọ rẹ lówà |