Skip to main content
Yorùbá Insights
Updated over 3 months ago

🎼 Níbiyíi ìwọ yóò rí díẹ̀ nínú àwọn ìmọ̀ràn tó tí ní ìlọsíwájú àti àwọn ẹ̀tàn fun ilowosi pípé ní èdè Yorùbá, nitorinaa, kò sí òhun tí o takò Awọn Itọsọna kikọ wá níbí, rántí là tí má fí sí lílo.


Àwọn Fáwélí àti kọńsónántì tí ó wà nínú èdè Yorùbá ✏️

Fáwélí Yorùbá pín sí ọnà méjì, àwọn náà níí

1. Àiranmúpè

2. Àránmúpè

* Fáwélí Àiranmúpè; À, E, Ẹ, I, O, Ọ, U

À - Ajá

E - Erin

Ẹ - Ẹyẹ

I - Imú

O - Owó

Ọ - Ọwọ

U - Ooru

* Fáwélí Àránmúpè; AN, EN, IN, ON, UN

Àpẹrẹ:

AN - Ìbhàdàn

EN - Ìyẹn

IN - Erin

ON - Ìbọn

UN - Ìbùsùn (bed)

kọńsónántì; B, D, F, GB, H, J, K, L, M, N, P, R, S, Ṣ, T, W, Y


Pàápàá, ìwúlò àmì èdè Yorùbá ṣe pàtàkì nínú lilo làti kò òrò èdè Yorùbá 💬

Aṣilo ọrọ

Àwọn ọrọ tó tọ́

Lilo nínú gbólóhùn ọrọ

Omo, omoh

ọmọ

ọmọ ológo

se, shey

ṣe

Ṣe o mọ pé mo féràn rẹ?

Oshey, ose

O ṣé

Oṣé gànn ní

Ise


Ìṣẹ́

Ìṣẹ́ mí ń lọ déédé

Aye

Ayé

J’yé lọ

Awon/ won


Àwọn/ wọn

Àwọn áńgẹ́lì/ wọn wípé

Ose, oshey

O ṣe

O ṣe lọpọlọpọ

Jowo

Jọwọ

Baby mí, jọwọ, jẹ ka

jọ má gbádùn

Jor, jo

Jọọ

Jọọ , má bínu

Ori


Orí

Orí mí gbémí débẹ

Emi-Mimo

Ẹmí-Mímọ

Ẹmí-Mímọ, jọwọ, bale mí

Owo, owoh

Owó

Torí owó ní kókó

Owo, owoh

ọwọ

Bàbá ọrọ àyé mí ọwọ rẹ lówà

Ogbon

Ọgbọn

Fi ọgbọn ọlọ́gbọ́n ṣe'gbọn

Fon

Fọn

Mo fí imú wọn fọn fèrè

Pon

Pọn

Jẹ kí ń pọ'mi síbẹ̀

Aso/aso

Aṣọ

Aṣọ funfun ni mo wọ

Did this answer your question?